Anglican Diocese Osun,
Omo Olorun ni wa,
Eje ka sise f'Oluwa,
Fun idagbasoke Anglican Diocese Osun.
Ere nbe feni to sise f'Oluwa
K'a fi imo Jesu s'agbara wa dotun,
k'a fi gbogbo okan wa sise to ye ka se,
k'a te le ipa ti Oluwa to,
ka' lo kede pe ofe nigbala,
k'a foritii, k'a foritii,
k'a reti, k'a ma s'ona,
Titi Oluwa yio fi de.
Titi Oluwa yio fi de,
Titi Oluwa yio fi de.